Yoruba Words For This Time!

Níwọ̀n ìgbà tí ó jẹ́ pé púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn àgbègbè yìí jẹ́ ẹ̀yà Yorùbá,ó ṣe pàtàkì láti sàmúlò àwọn èdè ìperí wònyí:

1. Quarantine
Ìsémọ́lé

2. Self-Isolation
Ìdánìkanwà

3. Coronavirus
Kòkòrò àìfojúrí kòrónà
4. Social distancing
Súnfúnmi-kí-n-súnfún-ẹ

5. Hand sanitizer ohun èlò olómi ìmọ́wọ́mọ́tóní.

6. Mask
Ìbomú-bẹnu

7. Gloves
Ìbọ̀wọ́

8. Ventilator
Ẹ̀rọ Amúnimí / ẹ̀rọ gbẹ́mìíró

9. Pandemic
Àjàkálẹ̀ Ààrùn(kárí àgbáyé)

10. Intensive Care Unit
yàrá ìtọ́jú alákànṣe
11. Fever - Ibà

12. Cough- Ikọ́

13. Sore throat - Ọ̀nà ọ̀fun dídùn

14. Tiredness/fatigue
Ara rírẹ̀

15. Aches
Ara ríro/Ara dídùn

16. High blood pressure
Ẹ̀jẹ̀ ríru

17. Underlying medical condition

Àìlera-abẹ́nú
18. Respiratory disease
Àrùn èémí

19. Lungs
Ẹdọ̀ fóró

20. Trachea/Windpipe
Ọ̀nà èémí ọ̀fun.
Ẹ ṣé púpọ̀.
You can follow @Olusegunverdict.
Tip: mention @twtextapp on a Twitter thread with the keyword “unroll” to get a link to it.

Latest Threads Unrolled: